Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha
Transkript
Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha
E ba wa dele E mo nipa wa ba wa sise Adiresi wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha Bi o ba fe Awon Iroyin to se koko Mo ti fegbe sile fun Bi olori ijoôba kan ba nilaari, to si jeô eôni apoônle to jeô eôni iyi funra reô, to ni itiju, to si moô ohun to n sôe, bi ko ba ri eeyan kan ba a rin laye moô ni Naijiria yii, sôe oômoô Sani Abacha ni yoo waa soô di oôreô imuleô ti woôn yoo joô maa woôle, ti woôn yoo joô maa jade. Nitori ki Jonathan sôaa tun le di aareô leôeôkeji yii, oômoô Abacha lo ku to n ba sôoôreô o. Titi di bi a sôe n wi yii, woôn ko ti i gba owo ti Abacha ji ko pamoô soke-okun tan, ojoojumoô ni awoôn ti woôn ko owo naa si loôdoô n fi oni donii ti woôn n fi oôla doôla, awoôn mi-in si n soô pe awoôn ko tileô moô ibi ti owo naa wa moô rara. Bakan naa ni awoôn mi-in n wa awoôn oômoô Abacha yii lati ba woôn sôeôjoô, nitori woôn ni orukoô woôn ni baba woôn wa fi ko owo naa pamoô, beôeô ni awoôn naa waa ko awoôn owo kan pamoô nibeô funra woôn. Nigba ti eleyii ba waa ri beôeô, sôe o waa yeô ko jeô awoôn oôta ilu bayii ni Jonathan yoo soô di oôreô bi! Bo ba sôe pe nibi ti ijoôba ti dara ni, to ba sôe nibi ti woôn ti n sôe ohun gbogbo letoleto, iru awoôn oômoô Abacha ti woôn ji owo ko loô sibi kan yii yoo wa leôwoôn, bi woôn ba si ti jade leôwoôn, ibi ti woôn yoo fi woôn si, eônu woôn ko ni i toôroô nibi kan. Sôugboôn ki la n ri laye Jonathan, awoôn oômoô ti baba woôn fi ogun ja ilu yii, awoôn lo ku toun naa n ba sôoôreô, awoôn lo ku to mu ni oludamoôran gidi. Gbogbo awoôn oniroyin lo gbe e pe Jonathan ati oômoô Abacha n sôepade pataki nile ijoôba. Arifin buruku, oôroô rirun, eôgbin oniyoôroô, gbogbo nnkan si dorikodo laye awoôn eeyan ti woôn ko moô kinni kan. Bi Jonathan ba tun woôle leôeôkeji bo sôe n soô pe oun feôeô woôle, sôebi awoôn ojulowo oôreô reô naa niwoônyi, iyeôn a waa tumoô si pe kekere ni iya to n jeô Naijiria lasiko yii, eyi ti yoo sôeôleô lati oôdun to n boô bo ba jeô oôkunrin to n pariwo kiri pe baba oun ko rowo ra bata foun nigba kan yii naa lo ba tun woôle yoo buru pupoô ju ohun ti eônikeôni ti ri loô. Ohun to han gbangba ni pe ijoôba yii ti dorikodo moô Jonathan loôwoô, gbogbo eôni to ba si feôran Naijiria, ki woôn soô pe ko maa loô ni. Amosun o, SDP lemi naa ti fee dupo Gomina—Igbakeji Gomina Nitori ti ko ri kaadi alalope re gba, Fashola ni INEC o sise won bii ise Ajimobi ko nilo ipolongo ibo fodun 2015 Emmanuel fi majele sinu ounje ayalegbe egbe e n'Ilorin Ibo abele da nnkan ru ninu egbe APC ati PDP nipinle Ogun Oro beyin yo ninu egbe PDP l'Ondo, alaga kowe fipo sile E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa
Benzer belgeler
Wahala niluu Etire: Won ni Kabiyesi ran agbanipa sawon ti
E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
Awon Baale Oke Pata, niluu Ifo so pe Olu Ifo fee da ogun
•Egbe awon baale nijoba ibile Ifo
O·ba Atanda tun soô pe,“Awa meôrin la pin
ipo O·ba Olu Ifoô laarin ara wa, awa naa ni: Ake, Oke-O·na, Gbagura ati Owu. A ki i loôoô foribaleô fun oôba
kankan ka to...